Iseda Ọ̀rọ̀ Orúkọ ni èdè Yorùbá

Ìṣe dá Ọ̀rọ̀ Orúkọ
1) Àwa Yoruba s'eda oro orúkọ nípa lílo afọmọ ibere, afọmọ àárín àti oro orúkọ méjì èyí ti aranmo máa ń ṣẹlẹ̀ nibe àti àpe tún pe kíkún

2) Àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda nípa lílo afọmọ ibere :ai àti òní.
Fún àpẹẹrẹ
Ai

Aiku

Ai
Jẹun
Aijeun

Ai
Lowo
Ailowo

Ai

Aila

Ai
Sun
Aisun

Ai
Gbogbo
Aigbagbo


3) iseda oro orúkọ nípa lílo afọmọ ibere òní àti orúkọ
Fún àpẹẹrẹ
Oni
Isu
Onisu

Oni
Ile
Onílé

Oni
Ata
Alata

Oni
Omo
Olomo

Oni
Aya
Alaya

Oni
Oko
Oloko


4) Iseda ọ̀rọ̀ orúkọ nípa lílo afọmọ àárín àti oro orúkọ méjì èyí ti aranmo máa ń ṣẹlẹ̀ nibe
Fún àpẹẹrẹ
Oro orúkọ
Afọmọ àárín
Ọ̀rọ̀ orúkọ
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda

Ìṣe
Ki
Ise
Isekise

Ilé
Ki
Ilé
Ilekile

Aṣọ
Ki
Aso
Asokaso

Ọmọ
Ki
Omo
Omokomo

Aya
Ki
Aya
Ayakaya


5) iseda oro orúkọ nípa pípa ọ̀rọ̀ orúkọ méjì pò láti di oro orúkọ kan.
Fún àpẹẹrẹ
Ọ̀rọ̀ orúkọ
Ọ̀rọ̀ orúkọ
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda

Etí
Odò
Etido

Eti
Ike
etile

Eti
Okun
Etíkun

Ojú
Ode
Ojúde

Ọmọ
Ọkùnrin
Ọmọkùnrin


6) iseda oro orúkọ èyí tí aranmo máa wáyé
Fún àpẹẹrẹ
Ọ̀rọ̀ orúkọ
Ọ̀rọ̀ orúkọ
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda

Ilé
Ìwé
Iléèwé

Ilé
Ìṣe
Ileese

Ara
Oko
Arooko

Àyà
Ọba
Ayaaba

Ìyá
Ègbé
Iyaegbe

Ara
Ilé
Araale


7) iseda oro orúkọ nípa lílo apetunpe oro ìṣe àti oro ìṣe láti di ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda
Fún àpẹẹrẹ

Àpólà oro ìṣe
Àpólà oro ìṣe
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda

Jagun
Jagun
Jagunjagun

Wole
Wole
Wolewole

Kólé
Kólé
Kokekole

Kọrin
Kọrin
Korinkorin

Pana
Pana
Panapana

Gbomo
Gbomo
Gbomogbomo

Tafa
Tafa
Tafatafa

Lagi
Lagi
Lagilagi

0 comments:

Post a Comment